Ìyàwó Ọ̀rẹ́ Mi


Am I thinking straight, Kemi?
Fún ọdún mẹ́ta báyìí, ìwọ ni ìyàwó kejì ọ̀rẹ́ mi
He introduced us, o sì rẹ́rìn-ín músẹ́,
i forgot about you until the trouble started
 kokoko ẹnu ilẹ̀kùn mi kò jẹ́ kàyéfì mọ̀ọ́

Am I being honest, Kemi?
You belong to a man who has been good to me
Ṣùgbọ́n èrò ọkàn mi ń sọ pé kí n kọtí ọ̀gbọ́in
But as you lay in my bed, tí a ń fara yí ra,
My head rumbles for reasons we are betraying our benefactor

Kílódé tí mi ò fi ṣòjòjò, Kemi?
you're all I think about even though it's not right
Ó ti di àṣà láti yọ́ jáde lọ́gọ̀njọ́
Ní gbogbo àfẹ̀mọ́júmọ́, I am sad as you're off to your matrimonial home
But I am happy because if beauty were time, you would be eternity!

KIDD🍷

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Renewable energy and the federal ministry of power; Improving access by consumers to hydropower

HOW TO GET THINGS DONE

HOW TO GET THROUGH MONDAY